Orin Dafidi 1

Orin Dafidi Yoruba Bible

1 Ibukun ni fun Okunrin na ti ko rin ni imo awon enia buburu, ti ko duro li ona awon elese, ati ti ko si joko ni ibujoko awon elegan 2 Sugbon didun inu re wa li ofin Oluwa; ati ninu ofin re li o se asaro li osan ati li oru 3 Yio si [...]

Orin Dafidi 2

Orin Dafidi Yoruba Bible

1 Ese ti awon orile ede fi nbinu fufu, ati awon enia ngbiro ohun asan? 2 Awon oba aiye kese jo, ati awon ijoye ngbimo po si Oluwa ati si Eni ororo re pe, 3 E je ki a fa ide won ja, ki a si mu okun won kuro li odo wa. 4 Eniti [...]